I have no problem taking one or two cups of coffee/cream (no sugar) with my breakfast. For example fasting blood sugar this morning is 5.4mmol/L whilst reading after two hours is 6.6mmol/L.
Mo ki ogbeni Stefajson pupo pe o ku ajaye lowo aisan ito suga. Iwuri nla gba ni eleyi je fun awa yoku ti aisan yi nba finra. Imoran temi ni wipe kio mase kare ninu ilana tio gunle lati bo lowo aisan. Mo ri eko ko. Emi na yio si gbiyanju lati se awokose ti ogbeni Stefanjson.